Simi Aluko ònkọ̀wé eré oníṣe àti akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ilẹ̀ Nigeria nkọ̀wé nípa ṣíṣe ẹ̀dá iṣẹ́ ọnà èyí tí ó sopọ̀ mọ́ ara wọn, tí a fi ọgbọ́n àtinúdá gbé kalẹ̀, tí ó sì jẹ́ ìwádìí òtítọ́ nípa ìgbé ayé.
No matching posts found.
Awọn agunbanirọ mẹta n wa bi opin yoo ṣe deba igbeyawo ọmọde ni orilẹ-ede Naijiria nipa kikọ iwe ẹhónú lati paarọ ofin rẹ.